A Yin Orúko Yín (Àdúrà)

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

Baba a bùkún fún-un yín lónî a gbée yín ga kòsí olórun míràn bíiyín kòsí olùgbàlà bíiyín.
Kòsí olùràpadà bíiyín. Kòsí oba bíiyín. Kòsí olúwa tó dàbí iyín.
Mò ún wò yín pèlú ìrètí, ayò, ìyanu àti ní ìjubà. Mo júbà iyín.

Mo bòwò mo gbée yín ga, mo gbée yín ga, èyin ló ye èyin nìkan ló ye láti gbà ìyìn mi mo fìjúbù mi fúun yín olórun. Asèdáà mi, oba à mi, olúwa à mi, olórun ùn mi, olàgbàlà mi, mo fi ìbùkún fún un yín. Jékí gbogbo oun tó wà nínú mi fún ìbùkún fún orúko mímó re.