A Gbéeyín Ga
Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: A Gbéeyín Ga
[Verse]
Oluwa oun gbogbo,
Alagbara
Oba awon oba,
ko s’eni bi re
Aseyi o’un,
Olododo
Oluwa mimo,
ko s’eni bi re
[Pre-Chorus 1]
A gbe oruko yin ga,
Eyin ni iyin at’ogo ye
Ni isokan,
agb’owo soke
[Chorus 1]
Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
af’ogo fun yin
Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
A ngbe lati yin yin
[Verse]
Oluwa oun gbogbo,
Alagbara
Oba awon oba,
ko s’eni bire
Aseyi o’un
Olododo
Oluwa mimo,
ko s’eni bire
[Pre-Chorus 2]
Olorun olotito,
Ti wa pelu wa ni irin ajo yi
Ni isokan,
agb’oun soke
[Chorus 2]
Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
Af’ogo fun yin
Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
Titi aiye,
[Chorus 3]
A Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
Af’ogo fun yin
Gbe yin ga,
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
A ngbe lati yin yin,
A ngbe lati yin yin.