A Gbéeyín Ga

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: A Gbéeyín Ga

[Verse] Oluwa oun gbogbo,
Alagbara
Oba awon oba,
ko s’eni bi re

Aseyi o’un,
Olododo
Oluwa mimo,
ko s’eni bi re

[Pre-Chorus 1] A gbe oruko yin ga,
Eyin ni iyin at’ogo ye
Ni isokan,
agb’owo soke

[Chorus 1] Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
af’ogo fun yin

Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
A ngbe lati yin yin

[Verse] Oluwa oun gbogbo,
Alagbara
Oba awon oba,
ko s’eni bire

Aseyi o’un
Olododo
Oluwa mimo,
ko s’eni bire

[Pre-Chorus 2] Olorun olotito,
Ti wa pelu wa ni irin ajo yi
Ni isokan,
agb’oun soke

[Chorus 2]

Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
Af’ogo fun yin

Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
Titi aiye,

[Chorus 3] A Gbe yin ga,
a gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo,
Af’ogo fun yin

Gbe yin ga,
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
A ngbe lati yin yin,
A ngbe lati yin yin.