Béèni yíò rí [Adúrà]
Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: A Gbéeyín Ga
Àmín, béèni yíò rí. Àmín jé oro asé. Gbogbo ìgbà tí a bá nse àmín sí adúrà nkan tán so ni wipe béèni yíò rí. Agbé owó wa sókè. A sibùkún fúun yín. A bòwò fúun yín adúpé lówo yín ní torí eyín ni olórun tíó dára ati olúwa olótìto. Eyín le dìwa mú, tí e sín tó wa sónà òtitó ní gbogbo ìgbà atí fún odún pípé. Eyín le mú wa lo sí ojó iwájú tó yè koro.
A bùkún fúun orúko yín. Efún wa ní ókùn àtagbára sí, láti lè se ifé yín. Efún wa ní àse ati agbára ní gbogbo orílè àgbáyé. Efún wa ní agbára láti oké orún wá, kí ogó le jé teyín nikán. Afé kí gbogbo èdá álàyè wárírì níwájúu yín, kí wón gbée yín ga. A sì fé kí gbogbo ènìyàn le mopé, eyín ní olórun alágbára, oba gbogbo ayé, àti àsèdá gbogbo ènìyàn. Ejé kí gbogbo ènìyàn mo títóbi agbára yín, afé kí wón mo isé árà àti isé iyánú tí énse.
Efún wa ní ore òfé láti lè ma gbéeyín sókè, láti bu olá fúun yín ní oun gbogbo tí àan se