Gba ìyin wa [Adúrà]
Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: A Gbéeyín Ga
Mo fi opé mi fúun yín. Jésù modúpé lówo yín. Olúwa mi modúpé. Olùdarí mi modúpé. Olúsèdá mi modúpé. Olórun mi, olúrápadáa mi, modúpé. Mojúbà yin. Mo gbé yín ga. Mo gbé yin gégè. Mo sì gbé yín ga. Eyín nìkan lóye láti gba ìyìn mi, mofi ibùkún fúun yín. Eyín nìkan lóye láti gba ìyìn mi, modúpé lówóò yín. Esé o, esé olúwa.