Sí O
Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: A Gbéeyín Ga
[Verse]
A gboju s’oke (okurin),
A gbowo s’oke (obirin)
A gbo’un soke ni iyin yin (ifohun sokan)
Ife wa fun o (okunrin),
Sii o (obirin)
Okun wa fun o (okunrin),
Sii o (obirin)
A f’aye wa fun ijosin yin (ifohun sokan)
[Chorus]
Sii o (obirin) [Sii o (okunrin)],
Sii o (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa,
Sii O
[Chorus]
Sii o (okunrin) [Sii o (obirin)]]
Sii o (okunrin) [Iwo nikan (obirin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa,
Sii o
[Verse]
A gboju soke (obirin),
Sii O (okunrin)
A gbowo soke (obirin),
Sii O (Okunrin)
A gbo’un s’oke ni iyin yin (ifohun sokan)
Ife wa fun o (okurin),
Sii O (obirin)
Okun wa fun o (okurin)
Sii O (obirin)
Af’aye wa fun ijosin yin (ifohun sokan)
[Chorus]
Sii O (obirin) [Sii O (okunrin)]
Sii O (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa,
Sii O
[Chorus]
Sii O (okunrin)
[Sii O (obirin)]
Sii O (okunrin) [Iwo nikan (obirin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa,
Sii O
[Prayer]
Mo bùkún fún O, mo bùkún fún O, mo gbé owó mi sókè sí ìté àti síwájú Re. Mo gbé okàn mi wá síwájú orúko mímó Re. Láti inú ayé mi àwon ohun mímó ndìde g’òkè sí Olórun. Láti inú ayé mi àwon ore mímó nsàn g’òkè sí O.
Mo gbé àwon ìrúbo opé, àwon èso enu mi nse ìdupé sí orúko Re.
Mo wá sìwàjù Re, mo sì mú ore mi wá fún O.
[Chorus]
Sii O (harmony) [Sii O (okunrin)]
Sii O (harmony) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa,
Sii O
[Chorus]
Sii O (okunrin) [Sii O (obirin)]
Sii O (okunrin) [Iwo nikan (obirin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa,
Sii O
[Ending]
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa,
Sii O
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa,
Sii O
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa,
Sii O
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa,
Sii O
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa,
Sii O
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa,
Sii O