A Júbá Re

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

[Àdúrà]

A júbà yin, a fì bùkùn fú un yín asì gbé orúko yín ga. A gbé owó wa sókè síi yín. Bí àwon bàbá wá ti se, àwon bàbá wá tí àgbanì. Wón gbe owó mímó won sókè sí olórun asèyí ówûn àti bí Hábákúkù se so ní òpò odún séyìn èmi ó ma yò, èmi yió sì kún fún ayò. Eyín olórun asèyí ówûn, ni agbáraà mi’ Eyín la gbára àwon arákùnrin àti arábìrin mi. e jékí esè mi múlè bíi ti àgbònrín. E fún mi ní okun àti agbára; E gbé mi sókè sí ibi gíga.

Nítorínà láti ìsinsìn yí lo, àántèsíwájú asì úndìde, a sìn gbe ojú wa sókè síi yín asìn rin nínú ògo yín, asì nfi ìbùkún fún orúko mímó yín

Adúpé fún òrò yín. Adúpé fún ìtónisónà yín. Adúpé fún bí e ti únkó wa ní mímòose. E jékí òrò olórun kí ó sòkalè sórí ilè olórâ nínú okàn wa. E jékí gbòngbò re sì múlè. Kí ó sì so èso rere ní okàn àwon ènìyàn mímó yín. Ní ogbongbòn, ogóta ogóta àti ogogórûn nínú ohun tí olórun.
adúpé olórun. Afi ìbùkún fúun yín. àmín.

[Ègbè]

A bùkún yín
A fìnyìn fún
A gbée yín ga títí ayé

Oba asèyí owú
Ìwo l’okun wa
A júba yín títí láí