A Yin Orúku Yín

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

[Ègbè]

Olúwa olórun ga agbée sókè
Oba àwon oba ga, agbée yín ga
Kò sí enìkan tó ga táa gbé sókè
A yin orúkoò re

[Ese ìkínní]

Gbogbo ágbara ni a fi fún olúwa
Òrò re ìyè, òfin ìre jé òtító
Ayé wa jé ìrúbo fún olúwa
A yin órukò re

[Ese kejì]

Jésù olúwa, a gb’órúko yín ga
Ayée wa únkéde ohun rere àti ìfé è re
Pèlú okàn ìmore a júbà
A yin orúkoò re