Bàléwa (Àdúrà)

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

Ejékí èmí mímó tí ó bàlé Jésù kíó bàlé àwa náà pèlú
E jé kí èmí olórun kíó sò kalè sí inú ayée wa
E jé kíó bàlé àwon ebí àti alábâgbé wa
E jé kí èmí tíó jé ti olórun kí ó darí ìgbésí ayé mi
E jé kí èmí mímó bàlé àwon aya, àti àwon Oko
E jé kí èmí mímó olórun bàlé àwon omo wéwé àti èwe
E jé kí èmí olórun bàlé àwon ará ìjo wa
Kí ó bàlé gbogbo wa ní àpapò, bí a se úntèsíwájú
ní nú àjòo wa, láti lè bá Olórun rìn títí dé òpin ayé
A ti pinu, pé a kòní bojú wèyìn, sùgbón a ó mãã rìn nínú èmí, títí òpin ìrìn àjò nãã

Béèni yíó sì rí, fún gbogbo ojó ayé wa . Àmín