Mímó Mímó

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

[Ègbè]

Mímó mímó
Mímó lolúwa
Mímó mímó
Mímó l’olúwa

[Ese ìkínní]

Olúwa a dúró ní wájúù re
Àwa tée dá pèlú okùn àti agbára
Àn úngbówó sókè fún oba àwon oba
Títí láí àti láíláí

[Ese kejì]

E ti f’èmí yín, sí inú wa
Ìsúraà yí ni àwa yó pamó
Ìbèrùu yín yó mà gbé núu wa
Títí láí àti láíláí

[Àdúrà]

Mo fì ìbùkún fú un yín. Mo fi ìbùkún fún ìwà mímó yín. Mo fi ìbùkún fún orúko mímó yín. Mo gbé ohùn mi sókè ni ayé, mosì fi ìbùkún fún yín. Mo gbé ohùn mi sókè látinú ògbun ayé yî, mo sì darapò mó àwon ti o wà nínú ayérayé láti gbéeyín ga àti láti fi ìbùkún fúun yín títí láilái. Mo dúpé fún oreòfé yín. Mo fi ìbùkún fúun yín.

Fìyìn fún olúwa ìwo ókan mí àti ohun gbogbo tó nbe nínú mi fi ìbùkún fún orúko mímó rè.