Mo Jú Bàa Re

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

[Ègbè]

Mo jú bàa re
Ìwo nìkan mò fifún
Ayé mi àti oun gbogbo
Pèlú okàn mi mo jú bàa re

[Ese ìkínní]

Fún wo nìkan ni mo júbà
Fún wo nìkan mo folá fún
Gbogbo okàn mi ni mo fi fún o
Pèlú ayé mi mo rúbo fun

[Ese kejì]

Èyín joba; lágbára àti okun
Èyín gúnwà lórí ìté
Àse yín bo orí oun gbogbo
Ní ìwárìrì ni mo wólè