Mojúbà Re (Àdúrà)

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

Mo júbàa yín, èyin nìkan soso ni ó tó gba ìjúbà wa, A fi Ògo Olá àti ìyìn fún èyin nìkan Mo júbàa yín

Mo gbée yín ga, Mo fi olá fún un yín, mo yìn yín lógo èyin nìkan ló tósí láti gba ìjubà mi, èyin nì kan ní ó ye láti gba ìyìn mi

Mo gbée yín ga, Mo júbàá yin, Mo fi ìbùkún fún un yín Jékí ohùn mi kún fún ìyìn inyín, nísìnsin ìn yì àti láíláí, Jékí okàn mi bùkún fún iyín lónî àti títí láíláí

Torí èyin nìkan ló tósí láti gba gbogbo ìyìn mi. kòsí enikéni, tàbí ohunkóun tí a lè wólè fún léyìn èyin nìkan “Mo jú bàa yín “ kòsì sí elòmíràn ní ayé yìí tàbí ní òrun tí alè júbà fúnèyí ni ìpinu wa títí láíláí Títí láíláí ni a ó màa júbà yín èyin olórun alágbára jùlo, èyin ni Oba únlá tí ó únsògo nínú àwon òrun

Mo jú bàa yín, èyin ni elédâ mí, olùràpadà mi àti olórun ùn mi. mo jú Bàa yín