Ònà Nâ

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

[Ese ìkínní]

A ò bòwò fún oun àtijó
O mú wa rìn nínú ònà t’énìkan ò rìn rí
Ànrí pa rè nínú èmí
Àwa únrí Oun tuntun tó lórun se

[Láti losí ègbè ìkínní]

Pèlú ìrètí okàn
Òpò oun nbú yo
Nípa ònà ti ìmúse
Ìfé re nyé wa yé ké

Aríbi àbò tó dá jú
Ore òfé titun nsàn wá
Agbára àti ogbón láti
Parí isé olúwa

[Láti losí ègbè ìkejì]

Olúwa jé káyé gbó ohùn re
Fa àyànfé mó ra
Nísòkan dìde ìmólè ti dé
Nínú olúwa ìmólè ti dè

[Egbe]

Báyî òkùnkùn bo aiyé
Kò sìsí eni tí óyé
Orísirísi yí wa káa
Tó nmi okàn gbogbo aiyé

A dúró láarín ológbón
Láarín àwon tó ndúró
Darí gbogbo ènìyàn
Sí won lójú èmí

[Orin ìparí]

A ò bòwò fún oun àtijó
O mú wa rìn nínú ònà t’énìkan ò rìn rí
Wíwà pèlú wa nídajú
P’ánà tá àánrìn yî yío jé ìlànà
Fún òpò ènìyàn