Títí Láíláí

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Ajúbà Re

[Ese ìkinní]

Agbára mí
Aláàbò mí
Igbóòyà mí
Mo gbékè mi lé o
Ìdùnú mi, ìsádi mí

[Ègbè ìkinní]

Mo gbé o ga títí aiyé, Olúwa
Mo jú bàre, Mo wólè fun
Mo gbé o ga, Olúwa
Mo jú bà re, mo wólè fun

[Ese keji]

Òtitó mi,
Ìtósónà mi
Olórun alágbára
Ìwo ni mo júbà a
Mo fì yìn fun
Tún térí ba

[Ègbè kejì]

Mo fì bà fun, Olúwa
Mo jú bà re, Mo wólè fun
Mo gbé o ga, Olúwa
Mo jú bà re, Mo wólè fun

[Àdúrà]

Òpò oun gbogbo tí a nse yîo wâ só pin, Sùgbón kí a ma júbàá yín yîo wà títí láíláí.
èyí ni a ó ma se títí ayérayé. Ìgbà tí a bá njúbà Olórun à nkó ohun tí a ó fi gbogbo ayérayé se ni.
Gbogbo ohunkóhun tó gba okàn wa yîo wà só pin, Sùgbón ká majúbà yín yîo wà títí ayérayé. àmín? nígbà gbogbo laó sì máa gbé okàn wa sókè síiyín títí láíláí. Tí a bá njúbà Olórun, à njé kó di mímò fún aiyé, ikú àti ìdibàjé pé e kò ní agbára lórí wa. Mo ti se ìpinu wípé títí ayérayé ni èmi ó maa fi ògo, òla, ìyìn àti opé fún orúko nlá yín. àmín!!!!

[Ègbè kéta]

A gbé o ga títí aiyé, Olúwa
A jú bà fun, a te rí ba
A gbé o ga, Olúwa
A jú bà fun, a te rí ba

[Ègbè kérin]

A fì bà fun, Olúwa
A jú bà re, a wólè fun
A gbé o ga, Olúwa
A jú bà re, a wólè fun