Ayo

Artist: Congress MusicFactory
Produced By: Congress MusicFactory
Album: Joy – Global Edition

Ayo re ni imole si okan mi
Ayo re, kun mi, so mi di pipe
Ayo Re, ti le okunkun lo
mu mi rin ona re
Ayo Re

Ni “waju Re, l’opo ayo wa
Mo kun f’ope, mo dupe titi lai
Ko’rin iyin – Iwo n’iye at’orin mi
Okun mi; Oluwa mi – layo mi

Ayo re, mu eru wiwo fuye
Ayo Re, fun mi l’okun ija
Ayo Re, mu mi se oro Re
Lati rin ona re
Ayo Re

Ni “waju Re, l’opo ayo wa
Mo kun f’ope, mo dupe titi lai
Ko’rin iyin – Iwo n’iye at’orin mi
Okun mi; Oluwa mi – layo mi

Ayo Re, f’itura s’okan mi
Ayo Re, fun mi n’ife ayika wa
Ayo Re, to mi si ojo Re
Lati rin ona Re
Ayo Re

Ni “waju Re, l’opo ayo wa
Mo kun f’ope, mo dupe titi lai
Ko’rin iyin – Iwo n’iye at’orin mi
Okun mi; Oluwa mi

Ni “waju Re, l’opo ayo wa
Mo kun f’ope, mo dupe titi lai
Ko’rin iyin – Iwo n’iye at’orin mi
Okun mi; Oluwa mi

– layo mi
iwo la ayo mi